Jaekel House
Ilé Jaekel | |
---|---|
Building | |
Type | Ilé-Ìgbé |
Architectural style | British colonial architecture |
Location | Èbúté Mẹ́ta |
Country | Nàìjíríà |
Address | 17, Federal Road |
Coordinates | 6°29′20″N 3°22′42″E / 6.4890°N 3.3783°ECoordinates: 6°29′20″N 3°22′42″E / 6.4890°N 3.3783°E |
Construction | |
Completed | 1898 |
Renovated | 2010 |
Floor count | 2 |
Ilé Jaekel jẹ́ ilé alájà méjì òyìnbó àmúnisìn tí ó wà ní ìlú Èbúté Mẹ́ta, ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Wọ́n kọ́ ilé náà ní ọdún 1898 sí orí ilẹ̀ tí ó pò kan tí wọ́n sì sọ ilé náà ní orúkọ olóògbé Francis Jaekel OBE tí ó jẹ́ alámòójútó àgbà fún ilé-iṣẹ́ Rélùwéè ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó fẹ̀yìn tì ní ọdún 1970.[1] Ilé Ilé Jaekel yi ni ó jẹ́ ilé adá àgbà tẹ́lẹ̀ ṣáájú kí wọ́n tó yi padà sílé àwọn òṣìṣẹ́ àgbà. Olùyàwòrán ilé Ọ̀jọ̀gbọ́n John Godwin ni ó tún ilé náà ṣe pẹ́lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé-iṣẹ́ àjọ Rélùwéè ní ọdún 2010.[2] Wọ́n ti sọ ilé náà di ilé ìṣẹ̀mbáyé kékeré tí wọ́n fi àwọn nkan bí àwòrán awọn lààmì-laaka, àwòrán àwọn agbègbè oríṣiríṣi , àwọn ìsẹ̀lẹ̀ tí ó ti wáyé ṣáájú òmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti lẹ́yìn òmìnira ayé ijọ́un láti ọdún 1940 sí ọdún 1970 síbẹ̀, àti awọn irinṣẹ́, ohun-èlò, aṣọ orísiríṣi àti awọn àwòrán ọlọ́kan-ò-jọkan tí ó jẹ mọ́ ilé-iṣẹ́ àjọ Rélùwéè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n ṣe lọ́jọ̀ síbẹ̀. Ilé yí náà tún ilé àlọ́ nípa ìgbéyàwó kan ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[3][4][5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Oludamola Adebowale (February 4, 2018). "The Untold Tales Of The HRM Train Coach". The Guardian. Archived from the original on March 16, 2022. https://web.archive.org/web/20220316094530/https://guardian.ng/life/the-untold-tales-of-the-hrm-train-coach/. Retrieved June 16, 2018.
- ↑ Kaye Whiteman (2013). Lagos: A Cultural and Literary History (The Slender Plant of Heritage), Volume 5 of Landscapes of the Imagination. Andrews UK Limited. ISBN 9781908493897. https://books.google.com/books?id=fcS_BAAAQBAJ&q=jaekel+house+lagos&pg=PT177.
- ↑ "Jaekel House". British Council. Nigeria. May 1, 2016. Retrieved June 16, 2018.
- ↑ UNESCO (2016). Culture: urban future: global report on culture for sustainable urban development (Sustainable development goals). UNESCO Publishing. p. 232. ISBN 9789231001703. https://books.google.com/books?id=l3P2DQAAQBAJ&q=jaekel+house+lagos&pg=PA232.
- ↑ Dolapo Aina (October 16, 2017). "Nigeria's pre-independence history rots away in Ebute Metta". The Guardian. Archived from the original on March 16, 2022. https://web.archive.org/web/20220316094127/https://guardian.ng/art/nigerias-pre-independence-history-rots-away-in-ebute-metta/. Retrieved June 16, 2018.
- ↑ Kayode Ekundayo (July 4, 2010). "Railway's 112-Year-Old Jaekel House is 'Young' Again". Daily Trust. Archived from the original on June 17, 2018. https://web.archive.org/web/20180617192830/https://www.dailytrust.com.ng/sunday/index.php/feature/3204-railways-112-year-old-jaekel-house-is-young-again. Retrieved June 16, 2018.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]"Jaekel House Mini Museum". Legacy. Archived from the original on 2020-11-25. Retrieved 2020-12-11. Àdàkọ:Authority control