Jump to content

Ilẹ̀ ọbalúayé Brítánìì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ilẹ̀ọbalúayé Brítánì)
British Empire
Flag of British Empire
Àsìá
Awon ile agbaye, ti o fi igbakan je ara Ile Obaluaye Britanii. Current British overseas territories are underlined in red.
Awon ile agbaye, ti o fi igbakan je ara Ile Obaluaye Britanii. Current British overseas territories are underlined in red.

Ilẹ̀ ọbalúayé Brítánìì (The British Empire) je awon itedo, amusin, protektoreti, ile agbefun, ati awon other agbegbe miran baun ti won je jijobale tabi mimojuto latowo orile-ede Britani, ti won bere pelu awon amusin okere ati ibujoko itaja that had originated with the overseas colonies and ibujoko itaja ti won je didasile latowo Ilegeesi ni opin orundun 16th ati ibere orundun 17th. O je ile obaluaye totobijulo ninu itan aye ati, fun igba to ju orundun kan lo, o je eyi to lagbarajulo laye. Nigba tio fi di odun 1922, Ile Obaluaye Britani joba lori awon eniyan to to legbegberun bi 458 eniyan, eyi to je ida kan ninu merin iye awon eniyan aye nigbana,[1] o si ni ile to toju 12,000,000 square miles (31,080,000 km2) lo: eyun ida kan ninu merin gbogbo ile Aye.[2]



  1. Maddison 2001, pp. 98, 242.
  2. Ferguson 2004, p. 15.