Ilẹ̀ Ọba Bakuba
Ilẹ̀ọba Bakuba (o tun nje Kuba tabi Bushongo)
Ifáárà: Àwọn kúbà náà ló ń jẹ Bushoong.
ÀÀYÈ WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ààrin gbungban gusu (Congo Zaire) ni wọ́n wà
IYE WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹgbẹ̀riún mẹ́tà-dún-lóguń ni wọn
ÈDÈ WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ede Bushhoog ló jẹ́ ẹ̀yà Bàǹtú ni wọn ń sọ
ALÁGÀÁGBE WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Biombo, lùbà, kasai, lenda, pyaang, àti Ngongo
ÌTÀN WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn Bushoog ni ẹ̀yà tó pọ jù ni kńbà.Baba-ńlá wọn ló tẹ ibẹ̀ dó. Abẹ́ Ìṣèjọba Shyaan kan soso bi gbogbo wọn wà. Òun ló ń darí wọn. Apá ìwọ̀-oòrùn ni wọ́n ti wá sí tí wọ́n etí Máńgò wọn bá àwọn ìwa àti kété sì parapọ̀ ṣe ìjoba kúbà.
IṢẸ́ ỌNÀ WỌN
Àwọn tí ń ṣe iṣẹ́ ọnà tí àwọn adarí ìjọba àti àwọn mẹ̀kúnǹu ń lò bí :-
- Ìlù ìbílẹ̀ tí
- Ìwo tí wọ́n fi n] mu ọti
- Ìjókòó ọba
- Idà ọba
- Ọ̀pá aṣẹ́ àti
- Abẹ̀bẹ̀ ọba
ỌRỌ̀ AJÉ WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Wọ́n ń pẹja
- Wọ́n ń hun aṣọ
- Wọ́n ń dáko pákí, àgbàdo àti ọka ̀ bàbà
- Obiǹrin wọ́n ń ṣòwo ̀ káàkiri agbègbè wọn
ÌṢÈLU WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn Bushoog ló ń darí Kuba. Olú ìiú wọn ni Nsheng. Ó le ní ọgọ́ruǹ-ún aṣojú fún ìgbèríko kọ̀ọ̀kan. Òfin ati ìlànà ọba Nyimu wọn ń tẹ̀̀ lé oba shyaam ni ọba àkọ́kọ́. Àwọn ọba mọ́kaǹlélógún ló sì ti jẹ lẹ́yìn rẹ̀. o ti ló iríniwó ọdún ṣẹ́yìn tie ̀tò ìjọba náà ti bẹ̀rẹ.
Ẹ̀siǹ WỌN
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bumba ni ẹdá àkọ́kọ́ nínú ìtàn ìgbà ìwáṣẹ̀ won. Òun ló fí awọn Bushoong se asíwájú àti olórí -Ẹ̀sin Baba ńlá wọn ni wọn ń sìn. Ẹ̀sín ọ̀ún ti ń ku lọ díẹ̀díẹ̀. Síbẹ̀, Ìfá tabi Adábigbá ń gbé láàrin wọn. Wọn gbà pè òròṣà ló ko oríre bá wọń. Ère ajá ni wọṅ ń sí ojúbọ òrìsà wọṅ . Ère yìí ló dúró bí olúgbàlà wọn.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |