Ìbínibí
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ilẹ̀abínibí)
Ìbínibí je agbajo awon eniyan ti won ni ibapinpo gidi tabi tikosi itan kanna, asa, ede tabi orisun.[1] Idagbasoke ati isegbejadeimo ibínibí je bibatan gbagbagba mo idagbasoke awon isejoba tonile-ese elero ayeodeoni ati awon egbe imurinkankan aseonibinibi ni Europe ni awon odunrun 18jo ati 19sa,[2] botilejepe awon asonibinibi n fa ibinibi lo si ijohun lori ila itan jijapo.[3]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nation", The New Oxford American Dictionary, Second Edn., Erin McKean (editor), 2051 pages, May 2005, Oxford University Press, ISBN 0-19-517077-6.
- ↑ Dictionary of the History of Ideas: s.v. "Nationalism"
- ↑ Fun apere imukede aigbarale ti awon ara Irelandi fa akitiyan awon ara Irelandi si ijobalelori awon ara Geesi de bi odun 700.