Ìlá-Ọ̀ràngún
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ila, Nigeria)
Ìlá-Ọ̀ràngún | |
---|---|
town | |
Country | Nigeria |
State | Osun State |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ila Orangun | |
---|---|
town | |
Coordinates: 8°1′N 4°54′E / 8.017°N 4.900°E | |
Country | Nigeria |
State | Osun State |
Government | |
Time zone | UTC+1 (WAT) |
Ìlá Òràngún (tàbí Ìlá) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìlú àtijọ́ ní ìpínlẹ̀ ọ̀sun, Nàìjíríà. Ó jẹ́ olú ìlú àwọn ìlú àtijọ́ tó jẹ́ orúkọ kan náà ní ìlú ìgbómìnà ti ará ilẹ̀ Yorùbá ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn ti orílẹ̀-èdè nàìjìríà. Ìlá Òràngún jẹ́ ìlú tó gbajúmọ̀ pẹ̀lú orírun ìlú tí wọ́n jọ ṣẹ̀ wá (àti orírun ) ti Òkè-Ìlá Òràngún, ó wà ní 7.5 miles (12 km) tí tí dé ilá oòrùn gúúsù.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Where is Ila Orangun, Osun, Nigeria on Map Lat Long Coordinates". www.latlong.net. Retrieved 2022-08-09.