Illbliss
Ìrísí
Illbliss | |
---|---|
Background information | |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Oga Boss |
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) | Rapper |
Years active | 2000–present |
Labels | CAPital Hill Music/The Goretti Company |
Tobechukwu Ejiofor tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ illbliss, jẹ́ olórin àti oníṣòwò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun sì tún ni adarí àgbà fún ilé-iṣẹ́ 'The Goretti Company'. [1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ NotjustOk. "The Goretti Company". NotjusOk. Retrieved 14 June 2015.