Ilu Epe
Ìrísí
Ìlú Ẹ̀pẹ́ jẹ ìlú kan gbòógì ti o gbajúmọ̀ n'ílẹ̀ Yorùbá ni ìpínlẹ̀ Èkó lápá ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Ẹ̀pẹ́ jẹ.[1] O tún jẹ olú-ìlú Ìjọba Ìbílẹ̀ Ẹ̀pẹ́ (Ẹ̀pẹ́ Local Government).[2]. Iṣẹ́ àgbẹ̀ àti ẹja pípa ni iṣẹ́ Ìbílẹ̀ wọn n'ilú Ẹ̀pẹ́.[3]
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Epe, Lagos". Wikipedia. 2006-04-19. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ "List of Towns and Villages in Epe L.G.A". Nigeria Zip Codes. 2014-03-11. Retrieved 2019-09-19.
- ↑ "Epe - Nigeria". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2019-09-19.