Imamuddin Punjabi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox religious biography Abu al-Fadhl Imāmuddīn Khān Barāwli Chhachhrī[1] (tí a tún mò sí Imamuddin Punjabi) (ó kú ní 1916) jé Indian ti mùsùlùmí Sunni onímò ìjìnlè tí ó se olùdásílè Jamia Miftahul Uloom.

Ìtàn Ìdílé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwon asááju Imāmuddīn Punjabi wá láti agbègbè Brawl, Bajaur.[2] Wón ti sí lo sí Chhachh, wón sì se ibùdó won sí Kāla Noor ní agbègbè BatalaPunjab.[3]

Ìgbésí ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Imāmuddīn Punjabi ní Batala, ìlú kan nínú ìpínlè Punjab[4] ní orílé-èdè India. Ó kó èkó ahādith pèlú Ahmad Ali Saharanpuri[5] tí ó sì parí èkó rè ní ilé-èkó ìbílè ti dars-e-nizami láti Darul Uloom Deoband.[6] Nígbà tí ó parí èkó rè ní ilé-èkó ìmò èsìn ti Deoband, Punjabi se ìpinnú àjosepò pèlú Fazle Rahmān Ganj Murādābādi ní Sufism.[7]

Punjabi sí lo sí Maunath Bhanjan ní 1298 AH.[8] Ó se ìdásílè Jamia Miftahul Uloom, ilé-èkó èsìn ìlú-mòóká ní ìpínlè Uttar Pradesh.[5] ní orílé-èdè India.

Punjabi pa ipò dà ní odún 1916 ní Mau nínú àpapò ìgbèríko United Provinces of Agra and Oudh.[5]

Isé ìwé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àgbéjáde àwon ìwé ni ìwònyí:[9]

  • al-Balāgh al-Mubīn
  • Tab'yīn al-Kalām fi daf' il-Khisām
  • Masābīh al-Itlā ala al-Tahrīm al-Tawājud wa al-Simā
  • Rabī al-Anwār
  • Eīdayn ki namāz ka waqt

Ìwé ìtàn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 15. 
  2. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 16. 
  3. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 17. 
  4. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. pp. 14, 16. 
  5. 5.0 5.1 5.2 Asir Adrawi (in Urdu). Tazkirah Mashāhīr-e-Hind: Karwān-e-Rafta (2 April 2016 ed.). Deoband: Darul Muallifeen. pp. 42–43. 
  6. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. pp. 27–28. 
  7. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 22. 
  8. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. p. 33. 
  9. Adrawi, Asīr. Wali-o-Shaykh: Mawlāna Imāmuddīn Punjabi. pp. 68, 71, 76, 79, 82.