Immanuẹlla

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Emmanuella in 2017

Immanuẹlla Samuẹli (a bi ni ọjọ́ kejì-le-lógún oṣù keje, ọdún 2010) orúkọ Ìnagijẹ ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn mo si ni Emmanuella o si jẹ ọmọdé ò dẹrin p'oṣonu lori ikanni Mark Angel lórí ẹ̀rọ alatagba YouTube. Ni ọdún 2017, ni ikanni awada Mark Angel lórí ẹ̀rọ alatagba YouTube di akọkọ irú rẹ̀ ti o jẹ́ wípé ọmọ Naijiria lo nii oun si ni àkọkọ ti yoo ni awon ololufe ti o to milionu kan ní iye. [1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Immanuẹlla Samueli jẹ ọmọ bibi Ipinle Imo ni apá ihà ila-oorun orílẹ̀-èdè Naijiria. A bi ni Port Harcourt ni Ipinle Rivers . [2]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Immanuẹlla bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àwàdà nigbati o pe ọmọ ọdun marun.

  1. Pulse News (28 July 2017). "MarkAngel Comedy, Emmanuella gets YouTube plaque for hitting 1 Million subscribers". Pulse Nigeria. https://www.pulse.ng/news/google-for-nigeria-markangel-comedy-emmanuella-gets-youtube-plaque-for-hitting-1/7zm8vwg. Retrieved 17 April 2019. 
  2. Odusanya (21 September 2018). "Emmanuella the talented child comedian". Legit Nigeria. https://www.legit.ng/amp/1193729-who-emmanuella-story.html. Retrieved 17 April 2019.