Ìdìmúlẹ̀
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Institutions)
Àwọn ìdìmúlẹ̀ jẹ́ àwọn òpó àti ọ̀nà ìṣe ètò àwujọ àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tó úndarí ìwà àkójọpọ̀ àwọn ẹnikọ̀ọ̀kan nínú ibi ìgbépapọ̀ kan. Àwọn ìdìmúlẹ̀ jẹ́ mímọ̀ pọ̀ mọ́ social purpose àti ìdúróṣinṣin, èyí tó kọ́ jáa ìgbésíayé àti èrò ẹnikọ̀ọ̀kan, àti nípa ṣiṣe àti gbígbéró àwọn ilànà-òfin tó úndarí ìwà àjọṣe àwọn ènìyàn.[1]
Àwọn irú ìdìmúlẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ìgbéyàwó àti Ẹbí (Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ àwùjọ ẹbí)
- Ẹ̀sìn (Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ àwùjọ ẹ̀sìn; Ẹ̀sìn aráàlú)
- Ẹ̀kọ́ (èyuùn jẹ́léosinmi, àgbàkejì, àti gíga. Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ àwùjọ ẹ̀kọ́)
- Àwọn ìdìmúlẹ̀ tonísáyẹ́sì (See also: Ọ̀rọ̀ àwùjọ sáyẹ́nsì)
- Àwọn Ilé ìwòsàn (Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ àwùjọ ìlera; Ọ̀rọ̀ àwùjọ ìwòsàn)
- Àwọn sístẹ́mù abófinmu (Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ òfin; Ìmòye ófin; Ọ̀rọ̀ àwùjọ òfin)
- Àwọn sìstẹ́mù ìjìyàs (Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ àwùjọ ìjìyà)
- Àwọn ilé ìwòsàn saikiatrik ati Asylums
- Iṣẹ́ ológun (Ẹ tún wo: Ọ̀rọ̀ àwùjọ iṣé ológun)
- Àwọn ilé akéde ati ilé ìròyìn (Ẹ tún wo: Media studies)
- Àwọn ilé-iṣẹ́ ẹ̀rọ àti Àwọn Ile-iṣẹ́ Alájọtà (Ẹ tún wo: Capitalism; Ìpín ṣe iṣẹ́; Àkósótọ̀ láwùjọ; Industrial sociology)
- Àwọn àgbájọ (Ẹ tún wo: interest groups; political parties; Internet groups and Virtual communities)
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ http://plato.stanford.edu/entries/social-institutions/ Stanford Encyclopaedia: Social Institutions