International Research Confederacy on African Literature and Culture
Ìrísí
International Research Confederacy on African Literature and Culture (IRCALC) jẹ́ ẹgbẹ́ àwọn òǹkọ̀wé, ọ̀mọ̀wé àti àwọn olùwádìí lórí ẹ̀rọ ayélujára. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ́ IRCALC lórí àwọn ìwé Áfríkà, wọ́n sì ń ran àwọn ilé isé, ẹ̀ka ilé-ìwé gíga àti ilé ìkàwé láti pín ìmọ̀ nípa Áfríkà láàrin ara . Àwọn adarí IRCALC ma ń ṣe àtúnṣe sí Journal of African Literature and Culture (JALC) àti Poetry (NP), àjọ Progeny (Africa Research) ni ó ṣàgbéjáde àwọn ìwé méjèèjì.