Ipa ajakaye arun COVID-19 lori ona ati asa adayeba
Ajakaye - arun erankorona odun2019-2020 ni ipa ojijji ati idaran lori awon ona ati eka asa adayeba. Idaamu ilera kariaye ati aidaniloju abajade lati odo ipa awon ajo bi eni kookan - ti a gba sise ati awon to daduro kaakiri eka naa. Awon eka ona ati asa adayeba n gbiyanju lati se agbateru gbangba ni igba gbogbo, ise lati pese aaye fun awujo si ohun asa adayeba; setoju aabo awon osise won, awon ikojopo ati awujo eda; nigbati o n fesi iyipada airotele ninu awose isowo pelu opin aimo.
Ni osu Keta ọdun 2020, opolopo awon ajo asa kaakiri agbaye ni o wa ni titipa laisi idaduro (tabi o kere ju pẹlu awọn iṣẹ wọn ti o dinku patapata), ati awon isafihan eniyan, awon isele, ati awon ise di fifagile tabi sun siwaju. Ni esi, awon akitiyan to lagbara tabi afikun ni won to seto nipase ise awon iru ero dijita, lati mojuto awon ise pataki pelu oro pooku, ati lati se akosile awon isele fun rarawon nipase awon ohun ini titun, pelu ise alatinuda titun latari ajakaye arun naa.
Opolopo awon eniyan kaakiri ajo yii ni yoo padanu awon ise agbase won fun igba die tabi titilai tabi ise won pelu orisisi iwon ikilo ati iranlowo owo to wa. Bakanna, igbiyanju owo lati odo ijoba ati awon alaanu fun awon osere yoo pese iyato gidigidi ati awon ipele ti o da lori eka ati orile ede naa. Gbogbo eniyan ni o beere fun ise asa lati pada, sugbon ni akoko aimo ati pelu ero pe oririsi iriri ni yoo gbajumo.
Awọn Opin ati ifagile
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni idamerin akoko ninu odun 2020, awon eka ona ati asa kaakiri agbaye fi awon ise gbangba won si ihamo ati leyin naa ni won tipaa patapata latari ajakaye arun na. Bere lati Orile ede China, Ila-Oorun Asia, ati lehinna gbogbo agbaye, ni ipari osu keta opolopo awo ajo asa adayeba ti di pipade, ati awon isele ona gbogbo ti di sisun siwaju tabi ifagile, boya atinuwa a bi nipase ase ijoba.Eyi pelu awon ile aworan, ile ikawe, ile ifi nkan pamosi, ati awọn musiọmu (ti a mo si GLAMs lapapo ), ati fiimu[1] ati awon eto mahounmaworan, itage [2] ati awon ise onilu, [3] irin ajo ere orin , ogba eranko, ati orin - ati awọn ajọdun-ọnà.
Ni tele awon iroyin yajoyajo nipa opin ati fifagile kaakiri agbaye bere lati osu keji ati iketa atẹle awọn iroyin ti nyara ni kiakia ti awọn pipade ati awọn ifagile kaakiri agbaye jakejado Kínní ati Oṣu Kẹta, tit di osun kerin, odun 2020, igba, ojo ati akoko ti ile ise asa yoo di sisi pada ko tii ni gbedeke kaakiri agbaye. . Bakanna, awon owo igba pipe yoo ko ipa gidigidi, yato si tele ti awon ile ise ko le ni anfani ebun owo bee. Bakanna, awọn ipa owo igba pipẹ lori wọn yoo yatọ si pupọ, pẹlu awọn iyatọ ti o wa tẹlẹ paapaa fun awọn ile-iṣẹ laisi inawo ẹbun ti n buru si. Iwadi lati osu keta toka pe, nigbati awon musiomu se gbalaye lati tesi gbangba leekansii, idi abewo awon ona ero si ise asa ko gbodo yi pada saaju ajakaye- arun - sugbon pelu ipinu pipapoda iru ise ona bee.Alaye fi ye wa wa pe adinku yoo de ba wiwa si awon aaye ti a pese, egbe nla alailagbeka (bii cinima), awon ise ojulowo, pelu alekun anfani fun awon ise gbagede tabi aaye nla (gege bii ogba eranko ati ogba ajara). Awon idi ti o se pataki lati fi okan awon eniyan bale lati pada si igbe aye tele ni, wiwa abere ajesara, gbigbese kuro lori ririn irin ajo, imo pe awon miran ti se abewo, boya awon ise ati ile ise wa ni gbagede ati ipese ohun ipawo sanitaisa. .
- ↑ "'Over one hour everything was cancelled' – how coronavirus devastated the film industry". https://www.theguardian.com/film/2020/mar/20/over-one-hour-everything-cancelled-coronavirus-impact-film.
- ↑ "Coronavirus and culture – a list of major cancellations". https://www.theguardian.com/culture/2020/mar/13/coronavirus-culture-arts-films-gigs-festivals-cancellations.
- ↑ "Classical music: let the Berlin Phil come to you". https://www.theguardian.com/music/2020/mar/21/home-listening-classical-music-online-livestream-at-home-coronavirus.