Jump to content

Isaac Teitei Nortey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Isaac Teitei Nortey
Orílẹ̀-èdè Ghana
IbùgbéUnited States
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Keje 1999 (1999-07-08) (ọmọ ọdún 25)
Accra, Ghana
Ìga183 cm
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed, One-Handed Backhand

Isaac Teitei Nortey jẹ elere tennis ta bi ni ọdun 1999 ti órilẹ ede Ghana to sin gbe ni US. Ni ọmọ ọdun marun dinlogun, Isaac jẹ ọdọmọde elere to pegede julọ ninu idije Junior tennis ti ilẹ afirica[1][2][3][4][5].

Igbèsi Aye elere naa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nortey ni a bi si Accra, Ghana. Oun kẹkọ lori Igbega ọmọ èniyan ati ẹkọ lóri ẹbi[6][7].

Íṣẹ ati Ipa rẹ gẹgẹbi elere tennis

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nortey bẹrẹ iṣẹ̀ rẹ gẹgẹ̀bi elere afi ẹsẹ gba koto dipè o bẹrẹ sini ṣiṣẹ gẹgẹbi èlèrè tennis nigba to pe ọmọ ọdun meje. Arakunrin naa kọkọ ṣèrè ni Tennis ti Lakedland Galindo. Elere tennis naa ti yege ninu idije mẹfa. Ni ọdun 2019, Nortey wa lara team elere tennis ilẹ ghana to kopa ninu Copu Davis Group IV ni Brazzaville, Congo[8][9][10][11].

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. https://www.tennisexplorer.com/player/nortey-0c11d/
  2. https://www.itftennis.com/en/players/isaac-nortey/800366053/gha/mt/S/overview/
  3. https://www.atptour.com/en/players/isaac-nortey/n0e5/overview
  4. https://www.sofascore.com/team/tennis/nortey-isaac-nortie/220911
  5. https://scores24.live/en/tennis/m-06-03-2023-nortey-isaac-nortie-loge-jack-h2h
  6. https://www.flashscore.com.ng/player/nortey-isaac/OvbtMgZ6/
  7. https://nevadawolfpack.com/sports/mens-tennis/roster/isaac-nortey/4648
  8. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2023-03-02. Retrieved 2023-03-08. 
  9. https://www.modernghana.com/sports/941061/tennis-ghana-to-take-part-in-davis-cup-in-congo-brazzaville.html
  10. https://mobile.ghanaweb.com/GhanaHomePage/SportsArchive/Ghana-to-compete-in-Davies-Cup-after-years-of-absence-757847
  11. https://allafrica.com/stories/201906240670.html