Jagunjagun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Jagunjagun jẹ́ akọni tí ó máa ń jagun, pàápàá jùlọ láàárín ẹ̀yà, ìlú tàbí ẹbí kan. Láẁujọ Yorùbá, a máa ń ní ìran jagunjagun, àwọn ni wọ́n sáàbà máa ń joyè Ajagun, tàbí Balógun