Jump to content

Jamilah Tangaza

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Jamilah TangazaÀdàkọ:Pronunciation níkejì Jamilah Tangaza) jẹ́ àkọ̀ròyìn àti ìmọ-ẹ̀rọ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ àkọ̀ròyìn BBC tẹ́lẹ̀, níbi tí ó ti ṣisẹ́ ní onírúurú àwọn ìpò ko tó di olórí Hausa service. Tangaza jẹ́ ẹlẹ́gbẹ́ tí Reuters institute fún ikẹ́kọ ti ìwé ìròyìn, university of Oxford àti ọmọ ẹgbẹ́ ti chatered management institute ti united kingdom [1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Unveiling the new Abuja (AGIS) Director, Jamila". newsexpressngr.com. News Express. Archived from the original on 12 October 2017. Retrieved 12 October 2017. 
  2. "Jamila Tangazah". Reuters Institute. Retrieved 25 April 2018.