Jump to content

Jared Leto

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jared Leto
Leto ní San Diego Comic-Con ti ọdún 2016
Ọjọ́ìbíJared Joseph Leto
26 Oṣù Kejìlá 1971 (1971-12-26) (ọmọ ọdún 52)
Bossier City, Louisiana, U.S.
Orúkọ míràn
  • Bartholomew Cubbins
  • Angakok Panipaq
Iléẹ̀kọ́ gígaSchool of Visual Arts
Iṣẹ́
  • Actor
  • musician
Ìgbà iṣẹ́1992–present
Works
Alábàálòpọ̀Cameron Diaz (1999–2003)
Valery Kaufman (2015–2022)
ẸbíShannon Leto (brother)
AwardsFull list[lower-alpha 1]
Websitethirtysecondstomars.com
Musical career
Irú orinAlternative rock
Instruments
  • Vocals
  • guitar
  • bass
  • keyboards
Labels

Jared Joseph Leto ( /ˈlɛt/ LEH-toh; tí a bí ní ọjọ́ kẹrindínlógbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1971) jẹ́ òṣèré àti olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ nínú iṣẹ́ òṣèré tí ó ti ń ṣe fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, àwọn àmì ẹyẹ bi Academy Award àti Golden Globe Award.[1] Pẹ̀lú pẹ̀lú, ó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ orin kíkó gẹ́gẹ́ bi ara àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rock band Thirty Seconds to Mars.[2]

Lẹ́yìn ìgbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré nínú fíìmù My So-Called Life (1994), Leto ṣeré nínú How to Make an American Quilt (1995), ó sì gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú fíìmù Prefontaine (1997). Ó tún ṣeré nínú àwọn fíìmù bi The Thin Red Line (1998), Fight Club (1999), Girl, Interrupted (1999) àti American Psycho (2000). Leto gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyìn ipa rẹ̀ nínú Requiem for a Dream (2000). Lẹ́yìn èyí, ó bẹ̀rẹ̀ sí ń gbajúmọ́ isẹ́ orin kí ó tó padà sí isẹ́ òṣèré pẹ̀lú Panic Room (2002), Alexander (2004), Lord of War (2005), Chapter 27 (2007), àti Mr. Nobody (2009). Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Academy Award for Best Supporting Actor fún ipa rẹ̀ nínú Dallas Buyers Club (2013). Láàrin ọdún 2016 sí 2022, ó ṣeré nínú àwọn fíìmù bi Suicide Squad (2016), Blade Runner 2049 (2017), The Little Things (2021), House of Gucci (2021), àti Morbius (2022).

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref> tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/> tag was found

  1. Whitham, Alexis. "Fantastic Transformations". California Film Institute. Archived from the original on February 2, 2014. Retrieved January 24, 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Rock Icons of the 21st Century". Kerrang! (1305): 42. March 24, 2010. "He is a man of many talents. Not only does he have an impressive CV that lists actor, director, songwriter and singer/guitarist for Thirty Seconds to Mars [...] among his specialist skills but, three albums into the band's career, he's now a bona fide rock god. And, perhaps more significantly, being accepted as one."