Alan S. Kaye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Jeremy Kaye)
Jump to navigation Jump to search

Alan S. Kaye


Kaye ti o je gbajugbaja onimo eda-ede ku ni 31/5/2007. Kaye ti sise ti o po lori ede Semitic. Ibi ti o ti n fi isinmi re se iwadii ni United Arab Emirate ni won ti ri i pe o ni kansa (Cancer) ni 1/5/2007 ti omo re, Jeremy Kaye, si gbe e wa si ile ni 22/5/2007.