John Dabiri
Ìrísí
John O. Dabiri | |
---|---|
Dr Dabiri | |
Ìbí | Toledo, Ohio |
Ará ìlẹ̀ | United States, Nigeria |
Pápá | Aeronautics Bioengineering Mechanical engineering |
Ilé-ẹ̀kọ́ | Caltech Stanford University |
Ibi ẹ̀kọ́ | Princeton University (B.S.E.) Caltech (Ph.D.) |
Doctoral advisor | Morteza Gharib |
Ó gbajúmọ̀ fún | Vortex formation Reverse engineering of jellyfish Applications to wind turbines |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | PECASE (2008) MacArthur Fellow (2010) Alan T. Waterman Award (2020) |
John Oluseun Dabiri[1] jẹ́ ọmọ Naijiria tó tún tan mọ́ ilẹ̀ America. Ó jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ tó ń rí sí ọkọ̀ òfurufú, òun sì ni ọ̀jọ̀gbọ́n alága ní California Institute of Technology (Caltech).[2] [3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedgoogle
- ↑ Dabiri Lab. John Dabiri. Retrieved 27 September 2019.
- ↑ Biological Propulsion Laboratory Archived 2011-09-03 at the Wayback Machine.. See the People page. Retrieved 23 July 2012.