Joy Olasunmibo Ogunmakin
Ayọ | |
---|---|
Ayọ ní National Theatre tí ó wà ni Warsaw, ní 19 oṣù kọkànlá ọdún 2008 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Joy Olasunmibo Ogunmakin |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Ayọ, Ayo. |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹ̀sán 1980 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Cologne, West Germany |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments |
|
Years active | 2001–present |
Labels |
|
Website | ayomusic.com |
Joy Olasunmibo Ogunmakin (tí á bí ni 14 September 1980), tí a mọ̀ sí Ayọ jẹ̀ ọ̀kọrin orílé èdè German, Ẹnití tí ó ma ń kọ orin silẹ àti òṣèré. Ó lo èdè Yorùbá láti tù orúkọ rẹ̀ tí ṣe JOY ni ede gẹ̀ẹ́sì sí èdè Yorùbá tíì ṣe Ayọ̀, èyí tí ó jẹ́ orúkọ àbísọ rẹ̀.
Debut album rẹ̀ tí ṣe Joyful, jáde ní ọdún 2006, èyí tí ó tí de Music recording sales certification Double-Platinun status ni orílé èdè France, Music recording sales certification Platinum ní Germany àti Poland, bákan náà Music recording sales certification Gold status ní Switzerland, Italy, àti Greece. Ilé iṣé orin Interscope ní ó ṣe alágbèkalè àwo orin rẹ̀ ní orílé èdè United States ni ojó kẹẹ̀dọgún oṣù kọkànlá ọdún 2007.
Wọ́n bí ni Frenchen èyí tí kò jìnà sí Cologne ní orílé èdè Germany, ọ sí ní ọmọ ọkùnrin tí orúkọ kọ rẹ̀ ń jẹ́ Nílé, tí ó bi ní ọdún 2005, ọ sí ní ọmọ Obìnrin tí í ṣe Billie-Eve ni oṣù keje odun,[1] Ó fún Olórinbkan tí orúkọ béè ni je Patrick Bart- Williams, èyí wọn tí wá ní ìpínyà.[2] ní oṣù kẹta odun 2017, ọ bí ọmọ kẹta tí orúkọ rẹ ní je Jimi-Julius èyí tí ó jẹ́ ọmọ kẹta.[3]
Kí ọdún 2002 tó parí, àti òun àti àwon mọ̀lẹ́bí rẹ̀ kó lọ sí Greenwich Village, apá kan ní Manhattan ni Newyork City.[4] Lọ́wọ́lọ́wọ́, ó ń gbé ní Brooklyn ni New York[5].
Lẹyìn èyí ni Ààre UNICEF tí orílé èdè Faransé, Jacques Hintzy, ṣe ipolongo ní ọjọ́ kẹrin Oṣù Kejì ọdún 2009 pé òun fí okọrin náà Jẹ Patron UNICEF tí yóò má jẹ́ kí ètò fún àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ lati ní ìmọ síwájú si ní àgbáyé.[6]
Ilé iṣé kàn ní orílé èdè Faransé Marin Karmitz MK2 ló ṣe àgbéjáde eré Ayọ̀ JOY, èyí tí ó jẹ́ èdè oníṣe tí ó wà fún aádọ́rún ìṣẹ́jú, tí ó lórí ìgbé ayé Ọ̀kọrin ní ọdún 2009. Raphael Duroy ní ọ jẹ Olùdarí Eré náà[7][8]
Àwọn Orin ti Ayo ti kọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Albums
Singles
DVDs |
EP
Contributions
Music videos
|
Àwọn fíìmù tí ó ti ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ayo Joy 2009 documentary
- Murder in Pacot (2015
- Volt (2016)[10]
Ẹ̀rọ amóhúnmáwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Summer of Soul (2013, French Arte TV)
- Mission Incognito: Ayo (2014, ARTE)
Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- European Border Breakers Awards 2008[11]
- Globes de Cristal Award, Best Female Singer 2014[12]
- Grand Prize for SACEM repertoire abroad
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ma rencontre avec le chanteur Patrice". Trucs de Nana. 29 July 2010. http://www.trucdenana.com/alaune/article/node/ma-rencontre-avec-le-chanteur-patrice,4304,0.html. Retrieved 29 July 2010.
- ↑ Thierry Coljon (16 October 2013). "La grande famille d'Ayo". Le Soir. http://www.lesoir.be/341334/article/culture/musiques/2013-10-16/grande-famille-d-ayo. Retrieved 10 November 2013.
- ↑ "Ayo". Facebook.com. Retrieved 6 October 2017.
- ↑ Chris Jordan (7 December 2007). "The future looks bright for Afro-German singer Ayo". Home News Tribune. http://www.thnt.com/apps/pbcs.dll/article?AID=/20071207/PULSE01/712070466/1070/PULSE. Retrieved 15 November 2007.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Ade-Brown, Lathleen (25 June 2015). "7 Things to Know About Nigerian-German Singer Ayo". Essence. Retrieved 1 October 2015.
- ↑ "La chanteuse Ayo devient marraine de l'UNICEF". UNICEF. 26 June 2015. https://www.unicef.fr/article/ambassadeurs-et-personnalites-engagees-pour-les-enfants. Retrieved 29 September 2015.
- ↑ "MK2 Catalogue". 14 July 2011. Archived from the original on 14 July 2011. Retrieved 6 October 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Clairefontaine sponsorise un documentaire sur Ayo". Stratégies.fr. 27 April 2009. Archived from the original on 17 June 2009. https://web.archive.org/web/20090617070214/http://www.strategies.fr/actualites/marques/116066W/clairefontaine-sponsorise-un-documentaire-sur-ayo.html. Retrieved 3 June 2009.
- ↑ "'Ayo: Live From Monte-Carlo' Featured As PBS Fund Raising Special During December". 28 October 2007. Archived from the original on 29 December 2007. Retrieved 8 October 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedvolt
- ↑ "EUROPEAN BORDER BREAKERS AWARDS 2008 – winners 2008". 17 January 2008. Archived from the original on 17 January 2008. Retrieved 6 October 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Meilleur interprète féminine:" Ayo" – Globes de cristal 2014– 10/03/2014 – D17". 11 March 2014. Archived from the original on 11 March 2014. Retrieved 6 October 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)