Kànga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Kànga jẹ́ ihò jíjìn kan tí a gbẹ́ sínú ilẹ̀ léte àti rí omi ilẹ̀ bu jáde fún Ìwúlò àti ìṣẹ̀mí ọmọnìyàn àti ẹranko. [1]

'Kànga ti won gbe ni odun 1847

Ìrísí Kànga[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kànga ni ihò nla tí a fi búlọ́ọ́kù àti sìmẹ́ntì mọ yíká ihò tí a gbẹ́ náà. Lọ́pọ̀ ìgbà ni wọ́n ma ń fi ìfami tí a so okùn mọ́ nídìí fa omi jáde láti inú kànga náà.[2].[3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Oram, Mr. Brian. "Well Water Problems Common Well Water Problems Water Testing- A Free Guide for Private Well Owners". Water Research Center. Retrieved 2019-12-31. 
  2. "What to Know About Owning a Home with a Well". Water-Right. 2018-04-20. Retrieved 2019-12-31. 
  3. "What Are the Differences between Well Water and Tap Water?". Water Filtration Systems. Retrieved 2019-12-31.