Kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A 52-week curriculum for a medical school, showing the courses for the different levels.

Nínú ètò ẹ̀kọ́, Kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ni ó túmọ̀ sí pààpin kókó ètò-ẹ̀kọ́ nínú ìlànà ikọ́ni.[1][2] Ó tún lè jẹ́ àgbékalẹ̀ pàtó tí ó dá lé ìrírí àti òye àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fún ìkọ́ni tààrà..[3] Kọ̀ríkúlọ́ọ̀mù ma ń kó kókó iṣẹ́, ohun èlò ìkẹ́kọ́ àti ọ̀nà ìṣe ìgbéléwọ̀n fún ètò ìkẹ́kọ̀ọ́ náà.[4]

Ọ̀nà tí Kọ̀ríkúlọ́ómù pin sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Kọ̀ríkúlọ́ọ́mù alákọsílẹ̀. Èyí ni kọ̀ríkúlọ́ọ́mù tí a kọ sílẹ̀, ṣe àgbéyẹ̀wò rẹ́, tí a sì pọn ní dandan láti máa tẹ̀lé nínú ìlànà ètò ẹ̀kọ́ wa gbogbo, yálà ní ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama, tàbí Fásitì.
  2. Kọ̀ríkúlọ́ọ́mù aláìkọsílẹ̀. Èyí ni kọ̀ríkúlọ́ọ́mù tí a kò ke gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀ ti dún, àmọ́ òun ni ìlànà ìkẹ́kọ̀ọ́ tí a kọ́ lọ́nà àìfojúrí. Àwọn ẹ̀kọ́ tí a lè kọ́ ní abala ètò ẹ̀kọ́ àìfojúrí ni àṣà , ìṣeàti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yálà nínú ilé-ẹ̀kọ́ ni tàbí iyàrá ìkẹ́kọ̀ọ́.
  3. Kọ̀ríkúlọ́ọ́mù tí ó yàtọ̀ sí ìkọ́ni. Èyí ni ṣe pẹ̀lú eré ìdárayá, orin kíkọ, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yóò rí ẹ̀kọ́ kan tàbí òmíràn mú níbi ìṣe náà. [5][6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Kelly 2009, p. 13.
  2. Wiles, Jon (2008). Leading Curriculum Development. p. 2. ISBN 9781412961417. https://books.google.com/?id=rX--P1YUgI0C&pg=PA2. 
  3. Reys, Robert; Reys, Barbara; Lapan, Richard; Holliday, Gregory; Wasman, Deanna (2003). "Assessing the Impact of Standards-Based Middle Grades Mathematics Curriculum Materials on Student Achievement". Journal for Research in Mathematics Education: 74–95. 
  4. Adams, Kathy L.; Adams, Dale E. (2003). Urban Education: A Reference Handbook. pp. 31–32. ISBN 9781576073629. https://books.google.com/books?id=OSdCOlR2Ad0C&pg=PA31. 
  5. Kelly, A. V. (2009). The curriculum: Theory and practice (pp. 1–55). Newbury Park, CA: Sage.
  6. Dewey, J. (1902). The Child and the Curriculum (pp. 1–31). Chicago: The University of Chicago Press.
  7. Braslavsky, C. (2003). The curriculum.