Kalu Ndukwe Kalu
Ìrísí
Kalu Ndukwe Kalu | |
---|---|
Kalu at the 236th U.S. Marine Corps Birthday Event, Maxwell Air Force Base, 2011 | |
Born | Abiriba, Nigeria |
Nationality | Nigerian-American |
Alma mater | Rutgers University, Atlanta University, Texas Tech University, Yale University |
Kalu Ndukwe Kalu jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ ìlú America, tó jẹ́ oníṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ òṣèlú. Ó sì tún jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n tó ń kọ́ Political Science àti National Security Policy ní Auburn University Montgomery,[1] àti ọ̀jọ̀gbọ́n ní University of Tampere, Finland[2]