Keke Maruwa
Ìrísí
Keke Márúwá tàbí kẹkẹ Napep je katakata ẹlẹsẹ mẹta ti afi nṣe kabúkabú ni orile-ede Nàìjíríà. [1] Wọn bẹrẹ lílò kẹkẹ yi ní ìgbà ti ọ̀gágun Mohammed Buba Marwa jẹ Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó ní abẹ́ ìṣàkóso ológun.
O kéré ni ìwọnba, osi gba ènìyàn mẹta lẹyìn pẹlú awakọ kan soso ni iwájú.
Etun wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The story of tricycle (Keke) in Nigeria". Tribune Online. 2021-04-10. Retrieved 2022-02-01.