Kel Ahaggar
Ìrísí
Kel Ahaggar Ihaggarren ⴾⵍ ⵂⴴⵔ | |
---|---|
1750–1977 | |
Àsìá | |
Àwòrán Kel Ahaggar Tuareg | |
Status | Àdàkọ:Infobox country/status text |
Olùìlú | Hoggar Mountains, Algeria |
Àwọn èdè tówọ́pọ̀ | Berber |
Ẹ̀sìn | Islam |
Ìjọba | Tribal Confederacy |
Amenokal | |
Ìtàn | |
• Kel Ahaggar established | 1750 |
• Under French suzerainty | 1903 |
• not recognized by independent Algeria | 1962 |
• terminated by Algerian Government | 1977 |
Àdàkọ:Infobox country/formernext | |
Today part of | Algeria |
Kel Ahaggar (Berber: ⴾⵍ ⵂⴴⵔ) (trans: "àwọn ènìyàn Ahaggar") ni àwọn ẹ̀yà Tuareg kan tí wọ́n gbé ní àwọn òkè Hoggar (àwọn òkè Ahaggar) ní orílẹ̀ èdè Algeria. Àwọn apìtàn gbàgbọ́ pé matriarch Tin Hinan ni ó dá ẹ̀yà náà kalẹ̀, ibojì rẹ̀ wà ní Abalessa. Wọ́n dá kalẹ̀ láàrin ọdún 1750. Ẹ̀yà náà ni agbára lọ́wọ́ ara wọn, kí ó tó di ọdún 1977, nígbà tí ìjọba Algeria gba agbára lọ́wọ́ wọn.
Èdè ẹ̀yà náà ni Tahaggart.