Kgosi Sechele I Museum
Ìrísí
Kgosi Sechele I Museum | |
---|---|
Kgosi Sechele Botswana Legacy (Wọ́n so Kgosi Sechele Museum I lórúkọ tẹ̀le) | |
Building | |
Location | Molepolole, Botswana |
Coordinates | 24°24′24″S 25°29′42″E / 24.40667°S 25.49500°E |
Kgosi Sechele I Museum jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní Molepolole, orílẹ̀ èdè Botswana. Wọ́n dá musíọ́mù náà kalẹ̀ ní ọdún, wọ́n sì si fún àwọn ènìyàn láti ma wá bẹ̀ ní ọdún 1992.[1] Àpẹẹrẹ àwọn ǹkan tí ó wà níbẹ̀ ni memorabilia tí ó jọ mọ́ David Livingstone (1813-1873).
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ète Kgosi Sechele Museum ni láti gbé àṣà orílẹ̀ èdè Botswana lárugẹ. Wọ́n da kalẹ̀ ní ọdún, àwọn ènìyàn abúlé Molepolole ti agbègbè kweneng sì ló kọ. Wọ́n sí musíọ́mù náà ní ọdún 1992.
Àwọn Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Sechele, Kgosi. "Establishment of Kgosi Sechele Museum (Molepolole)". Archived from the original on 1 December 2017. Retrieved 30 November 2017.