Jump to content

Kida Kudz

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kida Kudz
Orúkọ àbísọOlukayode Odesanya
Ọjọ́ìbíLagos, Nigeria
Ìbẹ̀rẹ̀Nigeria
Irú orinAfropop
Occupation(s)Singer
InstrumentsVocals
LabelsDisturbing London

Olukayode Odesanya, tí ó tún jẹ́ Kida Kudz,[1][2] jẹ́ olórin Afropop ọmọ Nàìjíríà tó ń gbé ní U.K.[3] Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó win ayẹyẹ kejì ti Peak Talent Show ní ọdún 2010.[4][5] Ó ti ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú Ms Banks, Burna Boy, àti Octavian.[6][7]

Ayẹ́ rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó kúrò ní Nàìjíríà láti lọ sí U.K. nígbà tí ó wà ní ọmọdún mẹ́rìnlá, láti lọ gbé pẹ̀lú bàbá àti ìyàwó bàbá ẹ̀. Kudz bẹ̀rẹ̀ sí ní fẹ́ràn àwọn orin tí wọ́n ń kọ ní ìlú náà bí i grime, U.K. rap àti chessy pop.[3]

  • Animalistic (2021)[11]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. The, Nation (4 February 2022). "I've been depressed for two years – Kida Kudz". The Nation. Retrieved 14 January 2023. 
  2. Ben, Homewood (19 February 2020). "Making waves Kidz Kuda". Music Week. Retrieved 14 January 2023. 
  3. 3.0 3.1 Nicolas-Tyrekl, Scott (7 February 2020). "Meet Kida Kudz, A Man On A Mission To Spread His 'Afroswank' Gospel". Complex. Retrieved 14 January 2023. 
  4. Akinwale, Akinyaode (12 March 2020). "If I Hadn't Made It In Music, I Would Have Been A Pornstar – Kida Kudz". The Guardian. Retrieved 14 January 2023. 
  5. Micheal, Abimboye. "Nigerian teenage rapper, Kida Kudz, graduates from U.K. College with distinctions". Premium Times. Retrieved 14 January 2023. 
  6. "Kida Kudz". BBC. 3 August 2018. Retrieved 11 January 2023. 
  7. David, Renshaw (27 February 2019). "Ms Banks video Coldest Winter Ever 2". The Fader. Retrieved 14 January 2023. 
  8. More, Branches (24 June 2022). "Kida Kudz and Mr. Dutch come up strong on their EP, "World Citizens"". Morebranches. Retrieved 14 January 2023. 
  9. Tela, Wangeci (24 June 2022). "Kida Kudz Mr Dutch World Citizen". The Native. Retrieved 14 January 2023. 
  10. Micheal, Aromolaran (26 June 2022). "KIDA KUDZ AND MR DUTCH RELEASE JOINT EP "WORLD CITIZENS"". Culture Custodian. Retrieved 14 January 2023. 
  11. James, Keith (9 April 2021). " Premiere: Kida Kudz Explores The Dehumanising Effects Of Prison On Powerful "Animalistic"". Complex. Retrieved 14 January 2023. 
  12. Murray, Robin (7 February 2020). "Kida Kudz Drops New Mixtape 'Nasty'". Clash Magazine Music News, Reviews & Interviews. Retrieved 22 April 2023. 
  13. Motolani, Alake (27 July 2021). "Kida Kudz toasts to his African roots on 'Top Memba'". Pulse Nigeria. Retrieved 15 January 2023.