Kiwahu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

KWAHU

Kiwahu

ÀÁYÈ WỌN

Wọ́n wà ní apá Àríwá Ghana

IYE WỌN

Wọ́n lé ní ẹgbẹ̀rún márún –lé lọ́gọ́ta.

ÈDÈ WỌN

Ède Akàn ti ẹ̀yà Twini wọn ń fọ̀

ALÁBÀÁGBÉ WỌN

	ANYI, Asante àti Fante

ÍTÀN WỌN

Ẹ̀yà Akan tó ń gbé Àríwá Ghana ni Kwahu. Ìjọba ńlá Akàn bẹ̀rẹ̀ ní nǹkan bí sẹ́ńtúrì mẹ́tàla] sẹ́yìn. Àsìkò yìí ni ìjọba ńlá Asanti bẹ̀rè òwò góòlù Àwọn ìpi]nlẹ̀ kéékèèke díde láti gba òmìnira lábẹ́ Denkyira lábẹ aláẹẹ Kumasi Àgbáríjọ Akàn sí lágbára ìsèlú àti ọrọ̀ aje.

ÌṢÈLÚ WỌN

	Ìdílé kọọ̀kan ló ní ètò ìṣèlú àti òfin wọn. Olórí okó wà, olórí àdúgbò wà, olori agbègbè wà, mọ́gàjí náà sì wà tó fi dorí ńla Asante. Agbàra ńlá jẹ̀ orírun rẹ̀ dà Asante nìkan tó le jẹ olórí agbègbè tábí ìlú. Títí di àsìkò yìí ni àwọn Asante ń kópa nínú etò ìSèlú Ghana 

IṢẸ̀ ỌNÀ WỌN

- Wọ́n máa ń ṣe Bojì lósọ̀ọ́

- Wọ́n ń gbégi lére. (wọ́n ń ìjòkó obínrin

- Wọ́n ń ṣe ìlèkùn tí a mọ̀ Akuaba

- Wọ̀n ń mọ ìkòkò

- Wọ́n ń hun aṣọ̣(Aṣọ kéúté tó gbajúmọ̀ jù ní ilẹ̀ Àfírikà

ẸSIN WỌN

- Ìtàn ìgbà ìwáṣẹ̀ wọn kan sọ pè ọlọ́ru ńlá wọn sún mọ wọn. Ó sì ń bá wọn ṣeré. porporo gígún odó tí àwọn arígnṕ wọn ń gún ló ń han ọlọ́run-ńlá wọ́n létí tó fi bínú fi òrin ṣe ibújókòó. Àwon Akan ń bá ọlọ́run-ńlá wọn sọ̀rọ̀ tààràtà. Oríṣíríṣòí (Abosom) Òrìṣà ni wọ́n mó pèlú wọ́n mó ọ̀run wọn òrìṣa obìrin náà wà nídìí ìgbèbí.