Kudirat Akhigbe
Ìrísí
Medal record | ||
---|---|---|
Women's athletics | ||
Representing Nàìjíríà | ||
Commonwealth Games | ||
Bàbà | 2002 Manchester | 4 × 400 metres relay |
Bàbà | 2006 Melbourne | 4 × 400 metres relay |
African Championships | ||
Fàdákà | 2002 Radès | 4 × 400 metres relay |
Kudirat Akhigbe (tí wọ́n bí ní 29 December 1981) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje eré sísá, tó sì máa ń sá eré irinwó mítà.
Ó gba àmì-ẹ̀yẹ onídẹ nínú ìdíje 4 × 400 metres relay ní 2002 àti 2006 Commonwealth Games, bẹ́ẹ̀ náà ni ó kópa nínú ìdíje ti ọdún 2002, tí kò sì dé eré àṣekágbà. Nínú ìdíje 2002 African Championships, ó parí pẹ̀lú ipò karùn-ún, nínú irinwó mítà, tó sì gba àmì-ẹ̀yẹ onífàdákà nínú ìdíje 4 × 400 metres relay.
Ìdíje rẹ̀ tó dára jù ni eré tó sá fún ìṣẹ́jú àáyá 51.60, èyí tó wáyé ní oṣù kẹfà ní ọdún 2001 ní ìlú Seville.[1]