Jump to content

Kunu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Kùnú

Kunu (ti a tun mọ si kununzaki ) jẹ jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìkan mimu ti o gbajumọ kakiri orílè-èdè Naijiria, pupọ julọ ni àríwá Naijiria. Wọn má ń sábà fi jéró tàbí ọkà se, nígbà míràn, wón ó lọ àgbàdo. Wọ́n ma ń se nípa rí rẹ jéró tàbí ọkà tí ó ti gbó sí omi fún ìjọ́ díè tí won ó sì lọ̀ ọ́ mọ́ odukwu, Atalẹ tàbí ata.