Láńre Hassan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Láńre Adéṣínà Hassantí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí' Ìyá Àwẹ̀ró, tí wọ́n ní Ọjọ́ kẹta oṣù kẹwàá ọdún 1950, (3rd October 1950) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìlú láti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Sinimá àgbéléwò èdè Yorùbá ní ó máa ń ṣe jùlọ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó máa ń kópa nínú tí èdè Gẹ̀ẹ́sì náà lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan. [1] Láti ìgbà tí ó ti kópa gẹ́gẹ́ bí Ìyá Àwẹ̀ró nínú eré orí tẹlifíṣàn tí ẹgbẹ́ òṣeré tíátà Òjó Ládípọ̀ máa ń ṣe ni Ìyá Àwẹ̀ró tí kópa nínú àìmọye sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá.[2]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ìlù Gángan
  • Iró Gunfun
  • Adélébọ̀
  • Àjẹ́ Mẹ́ta
  • Bàbá Lukudi
  • Ìyàwó Túndé
  • Igbá Ẹwà
  • Ìkúnlè Kèsán
  • Ìrírí Mi
  • Mama Láńre
  • Oníbárà
  • Àtànpàkò òtún
  • Èjìdé
  • Okùn Ẹ̀mí
  • Dókítà Alábẹ́rẹ́
  • Fadùn Sáyémi
  • Ire Ayé Mi
  • Eto Ikoko
  • Ìdájọ́ Mi Tidé
  • Ìṣọ̀lá Ọba-orin
  • Ògo-Ńlá
  • ṣadé Blade
  • Ògìdán
  • Ògo Idílé
  • Òkun Ìfẹ́
  • Orí
  • Jáwọ́ńbẹ̀
  • Ogbologbo
  • Ojabo Kofo
  • Pakúté Olórun
  • Boya Lemo
  • Back to Africa
  • Owo Blow: The Genesis
  • Aso Ásiri
  • Family on Fire
  • Omo Elemosho
  • Ayitale

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]