Jump to content

Lásún Ray

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọlásúnkànmí Ray Èyíwùmí tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Lásún Ray jẹ́ ọmọ bíbí ògbóntagì òṣèré Yorùbá tí ó ti di olóògbé Pa Ray Èyíwùmí, ó jẹ́ òṣèré, adarí eré, ati olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ìgba èwe àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Súnkànmí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù Kíní ní Ìpínlẹ̀ Kwara. Ó kẹ́kòọ́ gboyè jáde nínú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ Kọ̀mpútà.

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé ní ọdún 1972, àmọ́ tí ó gbé eré rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Kórdé. Ó tún gbé eré kan tí akòrí rẹ̀ ń jẹ́ The Bridge tí ó mu gba amì-ẹ̀yẹ ẹ̀yẹ ti AMVC ní ọdún 2018.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. highprofile (2018-09-20). "Lasun Ray's AMVCA award, click to know to whom he dedicates the award". High Profile. Retrieved 2020-11-29.