Lọ́ọ́yà Ọmọ Yorùbá
Àtòjọ Àwọn Agbẹjọ́rọ̀ tí wọ́n jẹ́ Ọmọ Yorùbá
Àwọn Lọ́ọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Yorùbá. A kọ ọdún tí wọ́n sí òkè orúkọ wọn
1880 Christopher Alexander Sapará Williams Òun ni ọmọ Nàìjíríà tí ó kọ́kọ́ di Lọ́ọ́yà
1892
Rotimi Olusomoha Aládé
1900
John Augustus Otunba Payne
1905
E.J. Alexander Taylor
1909
John Akinọla Òtúnba Payne
1910
Sir Adéyẹmọ Alákijà 1913 Ọláyímíká Alákijà
Ithiel K Ladipọ Doherty
Olaseeni Moore 1921 E. A Franklin
Alfred Latunde Johnson
E.M.E. Àgbètì
T.A. Dolierty
1922
Adédépò Káyọ̀dé
S.H.A. Baptist.
1923
Ayọ̀délé Williams
Steven Bánkọ́lé Rhodes
A.O.D. Dòsùnmú
Adébíyí Désàlú
1924
C.A. Harrison Ọbáfẹ́mi
Muhammed Lawal Basil Agusto
A. O. Àbáyọ̀mí
I.O. Caxton Martins
Rufus Adékúnlé Wright
Adégúnlẹ̀ Ṣóẹ̀tán
1925
F.O. Lucas
A. O. Thomas
Albert Horatus Akíntúndé Doherty
1926
J. Ọmọliyì Coker
Isaac Kúshìkà Roberts
F. Tátúndé Vincent
John Martins
1927
T. Ẹkúndayọ̀ Kusimo Ṣórìnọ́lá
Akínbọ́nà Sólúadé
1928
Samuel Ayọ̀délé Thomas
Frances Edney Euba
1929
Ọmọ́sànyà Adéfólú
Richard Adé-Ẹ̀yọ̀ Doherty
Hezekiah Ajayi Johnson (Alias Onibuwe)
Àlàbá Akéréle
1930
Abíọ́lá Akínwùmí
1931
Ògúnyẹmí Ẹbíkúnlé Ajọ́ṣẹ̀
1933
Olúwọlé Ayọ̀délé Alákijà
1934
Adébíyí Májẹ́kódùnmí
1935
Ọlájídé Ọláríbigbé Alákijà
1936
Akinọlá Adésọ̀gbìn
1940
Adélékè Adédoyin
Ladipọ Ọdúnsì
1941
Ọladipọ Moore
John Idowu Conred Taylor
1942
Christian Adéṣẹ́gun Wilson
Ọdúnbákú
Ọlátúndé Balógun
Bọ̀dé Thomas
1944
Àlàbí Taylor
1946
John Adéjùmọ̀ Kester
funsọ Blaize
Akíntóyè Tẹ́júosó
Ọbájẹ́nu Awólọ́wọ̀
1947
H.O. Davies
Ọlájídé Ṣómólú
S.A. Adéọba
Victor Ìlòrí
C.O. Awóyẹlé
S. Àyìnlá Abina
Rẹ̀mí Fàní-Káyọ̀dé
T.O.S. Benson
L.O. Fádípè
V.A. Déhìmọ̀
G.B.A. Coker
E.A. Caxton-Martins
1948
M.O. Oyàmádé
J.O. Kassim
O.A. Akántóyè
A.O. Lawson
Dúró Phillips
Àtàndá Fàtáì-Williams
O. Akínkúgbé
Abíọ́dún Akéréle
Ayọ̀ Rósìji
M.A. Adésànyà
V.O. Ẹ̀san
Basheer Agusto
1949
C.O. Madarikan
A.O. Lápitẹ́
D.O. A. Ògúntóyè
G.S. Sówèmímọ̀
J.O. Beckley
1950
Adé Mummey
S.O. Lámbò
Adégbóyèga Adémọ́lá
J.A. Adéfarasìn
S.L. Akíntọ́lá
L.J. Dòsùmú
Isin Shotire
D.M.O. Akínbíyi
C.O. Ògúnbánjọ
A. Òkúbádéjọ.
Ayọ̀ Òkúsàga
Oláyínká Ọlámosu
O.O. Ọmọlolú
H.M. Àllí-Balógun
A.M.A. Akinloyè
1952
A.G.O. Agbájé
Akinọlá Àgùdù
J.O. Ajíbọ́lá
B. Olówófóyèkù
E.B. Craig
E.O. Ayọ̀ọlá
1953
O. Ajọ́sẹ̀-Adéògún
S.A Ògúnkẹ́yẹ
D.O. Coker
Adéníran Ògúnsànyà
S.L. Dúrósarọ́
A.R. Bákàrè
S.B. Adéwùnmí
Adénẹ́kàn Adémọ́lá
S.D. Adébíyí
Adédàpọ̀ Adérẹ̀mí
A. E. Molajo
O. Ọ̀ráfidíyà
Ayọ̀ Richards
Àdùkẹ́ Moore
E.O. Fákáyòdé
G.B.A. Akínyẹdé
Andrew Ajíbọ́lá
1954
O.B. Akin Olúgbadé
A.F.O. Dábírí
S.A. Awólèsì
A. Adésidà
Kẹ́hìndé Ṣófọlá
Adédòkun Hastrup
J.A. Ọdẹ́kù
Búsàrí Òbísẹ̀san
O.A. Fájẹ́misìn
D.O. Ògúndìran
Káyọ̀dé Ẹ̀ṣọ́
Y.A. Jìnádù
S.O. Abudu
1959
B.O. Babalákin
Y.O. Àdìó
Ọláyínká Ayọ̀ọlá
Àbáyọ̀mí Olówòfóyèkù
Lọ́yà àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Williams Alexander Sapara Williams. Ó di agbẹjọ́rò ní odún 1880. Ọmọ Yorùbá nì Májísíréètì kìíní ní ilẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà ni Sir Olumuyiwa Jibalaru. Ọdún 1938 ni ó di Majísíréètì yìí. Òun náà ni ọmọ Nàìjíríà kìíní tí yoo di adájọ́ ilé-ẹjọ́ kóòtù gíga (High Court of Judge). Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí yóò di ‘Chief Justice’ ilẹ̀ Nàìjíríà ni Sir Adétòkunbọ̀ Adémọ́lá. Ọmọ Yorùbá ni Ọmọ-ọba Abẹ́òkúta ni.
Lọ́yà tí ó kọ́kọ́ gba ‘Senior Advocate of Nàìjíríà ‘Chief F.R.A. Williams. Ọmọ Yorùbá ni.
Lọ́yà obìnbìn àkọ́kọ́ tí ó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí yóò di adájọ́ ilé ẹjọ́ àgbà (High Court Judge) ní ilẹ̀ Nàìjíríà ni Mrs Modupẹ Ọmọ-Ẹboh tí ó jẹ́ ọmọ Akingbẹhin. Ọmọ Yorùbá ni.
Òbìnrin Nàìjíríà tí yóò gba oyè Senior Advocate of Nigeria’ nịmọ ọ tí ó jẹ́kọ́àkó Yorùbá nị̀mọ. ỌolankẹMrs Folake S
‘Attorney-General’ tị tí yóò jẹkọ́ Nàìjíríà àkọ́mọ‘O Nàìjíríạ̀ilè ni Dr di ‘President of̣kọ́ Aáfíríkà tí yóò kọ́ ilẹ̀mọlawale Elias Òun ni ọTeshim O Yorùbá nịmọthe International Court of Justices’. O di ‘Knight’ nị sọkọ́n yóò kọ́ Nàìjíríà tí wọmọyà ọLó Yorùbá nịmọSir Kitoyi Ajasa. O