Lagos Trade Fair Complex

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Lagos trade fair complex jé ibi itaja àti iraja tí o kalè sí ònà Eko sí Badagiri, titobi rè lé ní 350 hectare ile.[1] A kó ojà náà ní 1970s láti jé fún orílè-èdè Nàìjirià àti àwon orílè-èdè miràn. Ní odun 2002, àwon olutaja àwon ohun eso, parti moto àti àwon ojà miràn kó láti ojà Balogun lo sí ibi itaja trade fair náà. Ni òní, òpòlopò egbé olutaja ni ówà níbè, àwon bi Balogun Business Association, Auto Spare Parts And Machineries Dealers Association (ASPMDA), and àwon oluta ohun eso labé umbrella Association of Progressive Traders.

Zoran Bojovic ló ya aworan ibi itaja náà,[2] Energoprojecks sì ló ko. A si ní odun 1977. Ara àwon ilé tí o wa ni ibi itaja náà ni ilé ifihan àwon ojà méjì fun ìjoba apapo Nigeria ati ilé itaja fun àwon gbogbo ìpínlè ní orílè-èdè Nàìjíríà. Àwon ohun amulo miràn níbè ni ilé fun àwon oniroyin àti orita fún ayeye àti àjòdún.

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ezugwu, Obinna (March 1, 2021). "N10trn investments threatened by Lagos Trade fair concession". Business Hallmark. Retrieved September 10, 2022. 
  2. Sekulic, Dubravka (February 9, 2013). "Constructing Non-aligned Modernity: the Case of Energoprojekt". Academia.edu. Retrieved September 10, 2022.