Landmark Leisure Beach
Ìrísí
The Landmark Leisure Beach, tí ó wà ní Plot 3 àti 4 Water Corporation Road - VI jẹ́ àkọ́kọ́ ní ìlú Èkó tó jẹ́ aládàání iwájú etí òkun. Àwọn ẹ̀yà etí òkun yìí ni boardwalk láàrín Atlantic coastline, èyí tí ó mú ìjìnnà ààyè ti Landmark Village wáyé, ilé sí Hardrock Café, Shiro Restaurant, àwọn ọgbọ́ntarìgì Landmark Event Centre àti èyí tí wọ́n má dá lẹ̀ "Retail Boulevard". Ó ṣàjọ̀pọ̀ ẹgbẹ́ẹgbẹ̀rún àwọn eré ìdárayá àti àwọn iṣẹ́ eré ìdárayá èyítí ó ṣáájú fún àwọn àgbàlagbà àti àwọn ọmọdé. [1]
IṢẸ́ GBAJÚMỌ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lórí ilẹ̀ tàbí ní òkun, Landmark Leisure Beach ti kún pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ ṣíṣe fún àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí.
Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "landmarkbeach". landmarkbeach. Archived from the original on 2022-09-20. Retrieved 2022-09-15.