Leila Aman
Ìrísí
Leila Aman ni a bini ọjọ kẹrin leelogun, óṣu November, ọdun 1977 ni Arsi jẹ elere sisa ti ọna jinjin órilẹ ede Ethiopia[1].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2003, Leila kopa ninu ere gbogbo ilẹ Afirica to waye ni Abuja, órilẹ ede Naigiria ti arabinrin naa si gbè ipo kẹta[2][3].
Ni ọdun 2004, Leila kopa ninu marathon ti Dubai ni bi ti arabinrin naa si gbè ipo akọkọ[4].