Jump to content

Leila Nakabira

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Leila Nakabira
Ọjọ́ìbíLeila Nakabira
1993
Uganda
Iléẹ̀kọ́ gígaMakerere University, Kampala
Iṣẹ́Actress •
Scriptwriter •
Women activist
Gbajúmọ̀ fúnThe Forbidden (2018)

Leila Nakabira (bíi ni ọdún 1993) jẹ́ òṣèré àti ajìjàgbara fún àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè Uganda.[1][2] Òun ni olùdarí Lepa Africa Films. Òun ni olùdásílẹ̀ Nakabira for Charity Foundation.[3]

Nakabira gboyè nínú Quantitative Economics láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Makere University.[4]

Wọ́n yàán Nakabira fún àmì ẹ̀yẹ mẹ́ta: Best Golden Actress (Drama), Golden Most Promising Actor and Golden Discovery Actor níbi ayẹyẹ Golden Movie Award Africa tí wọ́n ṣe ní ọdún 2018.[5][6] Ní ọdún náà, wọ́n tún yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti Zulu Africa Film Academy Award fún ipa tí ó kó nínú The Forbidden[7]. Ó gbà àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ UDADA Women's Film Award ní ọjọ́ ogún, oṣù kẹwàá ọdún 2018.[8] Ní ọdún 2019, wọ́n yàán fún àmì ẹ̀yẹ òṣèré bìnrin to dára jù lọ láti ọ̀dọ̀ The African Film Festival (TAFF) Awards[9][10] àti Lake International Film Festival (LIPFF).[11]

Àwọn Ìtọ́kàsi

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "'Just do it' says Ugandan actress on African Women's Day". RFI. July 31, 2019. Retrieved November 3, 2020. 
  2. Murungi, Dorcus (February 6, 2019). "Curvy, sexy Ugandan women named new tourist attraction". Scoop. Retrieved November 4, 2020. 
  3. Ruby, Josh (November 5, 2019). "Fingers Crossed! Leilah Nakabira Kenya-bound for LIPFF awards". MBU. Retrieved November 3, 2020. 
  4. "Formal training and qualifications add depth to your natural talents". Daily Monitor. February 14, 2020. Retrieved November 3, 2020. 
  5. Ruby, Josh (May 23, 2018). "Leilah Nakabira nominated thrice in the 2018 Golden Movie Awards". MBU. Retrieved November 3, 2020. 
  6. "2018 Golden Movie Awards Africa nominations announced". ScooperNews. May 21, 2018. Retrieved November 4, 2020. 
  7. Ruby, Josh (October 22, 2018). "Leilah Nakabira bags first award at the UDADA Film Festival". MBU. Retrieved November 3, 2020. 
  8. Ruby, Josh (October 22, 2018). "Leilah Nakabira bags first award at the UDADA Film Festival". MBU. Retrieved November 3, 2020. 
  9. "Diana Nabatanzi Nominated In The African Film Festival Awards In US". GLIM. June 18, 2019. Archived from the original on November 4, 2021. Retrieved November 3, 2020. 
  10. Ruby, Josh (July 3, 2019). "Leila Nakabira and Claire Nampala win big at TAFF awards in USA". MBU. Retrieved November 3, 2020. 
  11. Ruby, Josh (November 5, 2019). "Fingers Crossed! Leilah Nakabira Kenya-bound for LIPFF awards". MBU. Retrieved November 3, 2020.