Jump to content

Library

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòwán ilé-ìkàwé

Ile ikawe je ibi akojopo orisirisi iwe, amohun mo aworan ti o rorun lati lo, ti kinsepe won wa fun pipate lasan. Eyi je ohun tin se akojopo ohun titun ti o ndahun ibeere ohun elo, lojoojumo fun awon ayawe lo.