Luis Alberto Riart

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Luis Alberto Riart
LUIS RIART.jpg
31st President of Paraguay
In office
March 17, 1924 – August 15, 1924
Asíwájú Eligio Ayala
Arọ́pò Eligio Ayala
Personal details
Ọjọ́ìbí June 21, 1880
Villa Florida
Aláìsí October 1, 1953 (aged 73)
Asunción
Nationality Paraguayan
Ẹgbẹ́ olóṣèlu Liberal

Luis Alberto Riart (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù kẹfà, ọdún 1880[1], ó sì kú ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 1953) jẹ́ àgbà òṣẹ̀lú orílẹ̀-èdè Paraguay àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Paraguay láti ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1924 sí ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹjọ ọdún 1924.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]