Jump to content

Mayowa Nicholas

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Máyọ̀wá Nicholas)

Àdàkọ:Infobox model

Máyọ̀wá Nicholas tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù karùn-ún ọdún 1998 (22 May 1998) jẹ́ gbajúmọ̀ aránṣọ-ṣoge ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni aránṣọ-ṣoge ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tí wọ́n ṣàfihàn ní níbi ipàtẹ oge ti Dolce & Gabbana, Saint Laurent, àti Calvin Klein.[1][2]

Máyọ̀wá Nicholas wà lára àwọn adíje àṣekágbá ìdíje Elite Model Look lọ́dún 2014, ó bá àwọn gbajúmọ̀ aránṣọ-ṣoge orílẹ̀ èdè Italy, Greta Varlese fà kànǹgbàn nínú ìdíje náà contest.[3][4]

Lọ́dún 2015, ó kọ́kọ́ kópa nínú ìpàtẹ aránṣọ-ṣoge fún Balmain, Calvin Klein, Kenzo, Hermès, àti Acne Studios.[5] Láìpẹ́, ó ti bá àwọn gbajúmọ̀ aránṣọ-ṣoge bíi Prada, Miu Miu, Versace, Chanel, Michael Kors, àti Oscar de la Renta ṣiṣẹ́.[6][7][8][9] Bẹ́ẹ̀ náà, ó ti kópa nínú ipàtẹ aránṣọ-ṣoge ti Dolce & Gabbana.[10]

Ó yẹ kó kọ́kọ́ kópa àkọ́kọ́ lọ́dún fún Victoria's Secret Fashion Show lọ́dún 2017, ṣùgbọ́n ìjọba orílẹ̀ èdè China kò fún un òun àti àwọn akopa kan ní ìwé ìrìnnà láti wọ orílẹ̀ èdè náà.[11][12] Ó wá pàpà kópa nínú nínú Victoria’s Secret Fashion Show lọ́dún 2018. [13]

Máyọ̀wá ló wà lára àwọn aránṣọ-ṣoge àádọ́ta, Models.com's "Top 50" models tó dára jù lọ ní àgbáyé.[14]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. https://www.elitemodellook.com/int/en/home/mayowa-nicholas-for-calvin-klein/index.htm
  2. "Nigerian Model Mayowa Nicholas Shows Us How a Gele Head Wrap Is Really Done". 
  3. https://www.elitemodellook.com/int/en/home/mayowa-nicholass-guide-to-lagos/index.htm
  4. "Interview With Past Elite Model Look Winners 2014 Mayowa Nicholas And Victor Ndigwe". Archived from the original on 2020-11-18. Retrieved 2020-11-13. 
  5. "Mayowa Nicholas - Vogue.it". Archived from the original on 2020-11-18. Retrieved 2020-11-13. 
  6. "Prada’s Casting Is More Diverse and Distinctive Than Ever". 
  7. FashionModelDirectory.com, The FMD -. "Photo feat. Mayowa Nicholas - Atelier Versace - Autumn/Winter 2016 Couture - paris - Fashion Show - Brands - The FMD". The FMD - FashionModelDirectory.com. 
  8. English, Vogue. "Chanel: Spring/Summer 2017". Archived from the original on 2018-06-22. Retrieved 2018-02-20.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Molvar, Kari (14 September 2016). "Model Beauty Secrets, From a New York Fashion Week Newcomer" – via NYTimes.com. 
  10. "Dolce & Gabbana F/W 2016 (Dolce & Gabbana)". 
  11. Animashaun, Damilola (21 November 2017). "Mayowa Nicholas Was Denied A Visa To China & Missed Her Victoria's Secret Debut". Archived from the original on 27 July 2019. Retrieved 13 November 2020. 
  12. "55 Victoria’s Secret Models Just Attended Their Photocall in Shanghai". 18 November 2017. 
  13. https://www.glamour.com/story/victorias-secret-fashion-show-models-2018
  14. "MODELS.com's Top 50 Models". models.com. Retrieved 2019-01-13.