Jump to content

Oṣù Kẹta

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti March)
Breviarium Grimani-Oṣù Kẹ́ta
Osù:| Kínní | Kejì | Kẹta | Kẹrin | Kàrún | Kẹfà | Keje | Kẹjọ | Kẹ̀sán | Kẹ̀wá | Kọkànlá | Kejìlá


Àdàkọ:Kàlẹ́ndà31Ọjọ́Bẹ̀rẹ̀NíỌjọ́ Ẹtì

Osù keta (tí àwọn Yorùbá mọ̀ sí Oṣù Ẹrẹ̀nà) jẹ́ oṣù kẹta odun kalenda Gìrẹ́górì àti Julian. Ọjọ́ mokanlelogbon ni o wa ninu Oṣù Ẹrẹ̀nà. Òun ni oṣù kẹ́jì nínú àwọn oṣù méje tí ó ní ọjọ́ mókanlélogún.