Jump to content

Margaret Etim

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use Nigerian English Margaret Etim tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1992 jẹ́ asáré ọmọ Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ nínú eré ìwọ̀n irínwó mítà 400 metres .[1] Ó gba àmìn-ẹ̀yẹ lọ́dún 2010 nínú ìdíje àgbáyé àwọn ọmọdé, yàtọ̀ sí àwọn àmìn-ẹ̀yẹ tí ó dìjọ gbà pẹlu awọn akẹgbẹ rẹ̀ nínú ìdíje eré gbagigbagi 4 × 400

Ìdíje tí ó ti yára jù ní ti èyí tí ó wáyé ní Makurdi lọ́dún 2010, tí ó gbà á ní ìṣẹ́jú-àáyá 51.24.

Àwọn àṣeyọrí ìdíje rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Representing Nàìjíríà Nàìjíríà
2010 World Junior Championships Moncton, Canada 2nd 400 m 53.05
5th
2nd 4 × 400 m relay 3:31.84
African Championships Nairobi, Kenya 1st 4 × 400 m relay 3:29.26
Commonwealth Games Delhi, India 7th 400 m 52.66
4 × 400 m relay DQ
2011 African Junior Championships Gaborone, Botswana 3rd 400 m 53.23
2nd 4 × 400 m relay 3:38.87
World Championships Daegu, South Korea 7th 4 × 400 m relay 3:29.82
All-Africa Games Maputo, Mozambique 7th 400 m 53.15
2012 African Championships Porto Novo, Benin 1st 4 × 400 m relay 3:28.77
2015 African Games Brazzaville, Republic of the Congo 5th 400 m 52.64

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. IAAF profile for Margaret Etim