Jump to content

Mariam Alhassan Alolo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Hajia Mariam Alhassan Alolo commonly known astí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí "Haji Mariam" jẹ́ oníṣòwò àti ajíhìnrere Mùsùlùmí tí wọ́n bí sí ìlú Changli, ní agbègbè Tamale, ní Ghana ní ọdún 1957. Ó ṣe ìdásílẹ̀ Mariam Islamic Center ní Sabonjida, ní ọdún 1981 láti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àwọn obìnrin oníwàásù.

Mariam Alhassan Alolo

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Haji Mariam was a recipient of the Nana Asma'u Bint Fodio's Award for Excellence in Promotion of Literacy granted to her in 2008 by the Al furqaan Foundation, an excellence awards organization that honours Muslim individuals and organizations in Ghana.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "AL FURQAN FOUNDATION". Archived from the original on 25 July 2013. Retrieved 1 April 2014. 
  2. Pade Badru, Brigid M. Sackey (May 23, 2013). Islam in Africa South of the Sahara: Essays in Gender Relations and Political Reform. Amazon.com: Scarecrow Press. pp. 428. ISBN 9780810884700. https://books.google.com/books?id=BQx9lqZheggC&pg=PA173.