Jump to content

Mark Hamill

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mark Hamill
Hamill ní San Diego Comic-Con ti ọdún 2019
Ọjọ́ìbíMark Richard Hamill
25 Oṣù Kẹ̀sán 1951 (1951-09-25) (ọmọ ọdún 73)
Oakland, California, U.S.
Iléẹ̀kọ́ gígaLos Angeles City College (AA)
Iṣẹ́
  • Actor
  • voice artist
  • writer
Ìgbà iṣẹ́1970–present
WorksFull list
Political partyDemocratic
Olólùfẹ́
Marilou York (m. 1978)
Àwọn ọmọ3
Signature

Mark Richard Hamill ( /ˈhæməl/; tí a bí ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹsàn-án ọdún 1951) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà àti olùkọ̀wé. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Luke Skywalker nínú àwọn eré Star Wars. Ó bẹ̀rẹ̀ ní original 1977 film wọ́n sì fun ní àmì ẹ̀yẹ Saturn mẹ́ta fún ipa rẹ̀ nínú The Empire Strikes Back (1980), Return of the Jedi (1983), àti The Last Jedi (2017). Ó ṣeré nínú àwọn eré míràn bi Corvette Summer (1978) àti The Big Red One (1980). Ó tún farahàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré láàrin ọdún 1980 sí 1989.

Hamill ti kó ipa gẹ́gẹ́ bi Joker nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré tí DC Comics ṣe, ọkàn lára wọn ni Batman: The Animated Series in 1992. Ó jẹ́ ọ̀kanj lára òṣèré, tí o jẹ́ Hobgoblin nínú eré Spider-Man, Fire Lord Ozai nínú 'Avatar: The Last Airbender, àti Skips nínú Regular Show.