Jump to content

MediaWiki:Movepagetext

Page contents not supported in other languages.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Fọ́ọ̀mù ìsàlẹ̀ yìí ṣàtúnṣọlórúkọ ojúewé, yíò kó gbogbo ìtàn rẹ̀ sí ojúewé tuntun. Àkọlé rẹ̀ tẹ́lẹ̀ yíò di ojúewé àtúndarí sí ọ̀dọ̀ àkọlẹ́ tuntun. Ẹ lè ṣọdọ̀tun àwọn àtúndarí tí wọ́n tọ́kasí àkọlé tìbẹ̀rẹ̀ fúnrararẹ̀. Tí ẹ kò bá fẹ́ ṣèyí, ẹ ríi dájú pé ẹ kíyèsí ẹ̀mejì tàbí àwọn àtúndarí jíjá. Ojúṣe yín ni pé àwọn ìjápọ̀ ún tọ́kasí ibi tó yẹ kí wọn ó lọ sí.

Ẹ kíyèsí pé ojúewé ní yípò tí ojúewé mìíràn bá wà tó ní orúkọ ojúewé tuntun ọ̀hún, àyàfi tó bá jẹ́ òfo tàbí àtúndarí tí kò sì ní ìtàn àtúnṣe ṣẹ́yìn. Èyí túmọ́sí wípé ẹ lẹ̀ ṣàtúnṣọlórúkọ ojúewé padà sí ibi tó ti jẹ́ ṣíṣàtúnṣọlórúkọ wá tí ẹ bá ṣe àṣìṣe, àti pé ẹ kò le ṣàkọléṣórí ojúewé tó wà.

Ìkìlọ̀! Èyí le fa ìdàrú sí ojúewé tó gbajúmọ́; ẹ ríi wípé ohun tí yíò ṣẹlẹ̀ ye yín kí ẹ tó tẹ̀síwájú.