Medina Armino
Ìrísí
Sport | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Erẹ́ìdárayá | Athletics |
Event(s) | Long-distance running |
Medina Deme Armino jẹ elere sisa ti ọna jinjin ti órilẹ ede Ethiopia. Ni ọdun 2019 ati 2020, Medina yege ninu Marathon ti Xiamen to waye ni Xiamen, China[1][2].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2019, Medina yege pẹlu wakati 2:27:25, Ni ọdun 2020, arabinrin gbiyanju lori wakati rẹ si 2:26:12.
Ni ọ̀dun 2018, Medina kopa to si yege ninu Marathon ti Treviso pẹlu wakati 2:33:17 ati Marathon ti Beirut pẹlu wakati 2:29:30[3][4].