Merina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

MERINA

Àwọn ti won n so ede wọ̀nyí jẹ́ ará Malayo-Indonesian. Wọ́n ní ìtàn tó gbọ̀ọ̀rìn nípa ìsẹ̀dá wọn ati nipa àṣà àtí ètò òsèlú won láàrin orisi awọn ènìyàn Madagascar. Ẹsin kiriyo ati ẹ̀sìn eranko ni wọn ni sìn