Meseret Belete

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Meseret Belete Tola ni a bini ọdun kẹrin dinlọgbọn, óṣu september, ọdun 1999 jẹ elere sisa lobinrin. Arabinrin naa ṣóju fun ilẹ Ethiopia ni ere ilẹ Afirica ni ọdun 2019 ni Rabat. Meseret gba ami ẹyẹ ọla ti idẹ ninu idaji marathon ti awọn óbinrin[1].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọdun 2018, Meseret yege ninu idaji Marathon ti Gothenburg to waye ni Sweden. Ni ọdun 2018, Arabinrin naa kopa ninu idije Agbaye ti Idaji Marathon tonwaye ni Valencia, Spain to si gbe ipo kẹfa ninu ere awọn óbinrin nibi to ti gba ami ẹyẹ ti ọla wura pẹlu wakati 3:22:27[2]. Ni ọdun 2019, Meseret kopa ninu ere ilẹ Afirica to waye ni Rabat, Morocco to si gbe ipo kẹta.

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Meseret BELETE Profile
  2. 2018 IAAF World Half Marathon Championships