Mẹ̀túsélà
Mẹ̀túsélà (Hébérù: מְתוּשֶׁלַח / מְתוּשָׁלַח, Modern Mətušélaḥ / Mətušálaḥ Tiberian Məṯûšélaḥ / Məṯûšālaḥ ; "Man of the dart/spear", or alternatively "when he dies/died, it shall be sent/has been sent") ni eni to gbo julo ti Bibeli so ojoori re, o so pe o je odun 969.
Metusela ninu Bibeli
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Metusela je didaruko ninu Bibeli ni Genesis 5:21-27, gege bi akoole iran to ja Adamu mo Noah. Akoole iran yi tun je pipe, lai so akoole asiko, ni 1 Chronicles 1:3, ati ni Luke 3:37.
(21) Enoku si wa ni ogota odun o le marun o si bi Metusela. (22) Enoku si ba Olorun rin ni odunrun odun leyin ti o bi Metusela, o si bi awon omokunrin ati awon omobinrin (23) Gbogbo ojo Enoku si je irinwo odun o din marundinlogoji (24) Enoku si ba Olorun rin, oun ko si si, nitori ti Olorun mu lo. (25) Metusela si wa ni ogosan odun o le meje, o si bi Lameki (26) Metusela si wa ni egberin odun o din mejidinlogun leyin igba ti o bi Lameki, o si bi awon omokunrin ati awon omobinrin (27) Gbogbo ojo Metusela si je egberun odun o din mokanlelogbon, o si ku
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |