Mítà
(Àtúnjúwe láti Metre)
Jump to navigation
Jump to search
Mítà tabi meter tabi metre je eyo tìpìlẹ̀ ìwọ̀n ìgùn ninu Sistemu Kakiriaye fun awon Eyo (SI).
Awon eyo mita ipin ati asodipupo ti a n lo ni wonyi:
- pm mitarondo (pikometre) = 10-12
- nm mitalanko (nanometre) = 10-9
- µm mitatintinni (maikrometre) = 10-6
- mm ipinlegberunmita (milimetre) = 10-3
- cm ipinlogorunmita (sentimetre) = 10-2
- dm ipinledimita (desimetre) = 10-1m
- km egberunmita (kilometre) = 103m
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |