Mfon Udoka
Ìrísí
Forward | |
Personal information | |
---|---|
Born | 16 Oṣù Kẹfà 1976 Portland, Oregon, U.S. |
Nationality | American / Nigerian |
Listed height | 6 ft 0 in (1.83 m) |
Listed weight | 187 lb (85 kg) |
Career information | |
High school | Benson (Portland, Oregon) |
College | DePaul (1994–1998) |
NBA draft | 1998 / Undrafted |
Career history | |
1998 | Detroit Shock |
2003 | Houston Comets |
2004 | Los Angeles Sparks |
Mfon Sunday Udoka (tí a bí ní ọjọ́ kerin-dín-lógún, oṣù kẹfà ọdún 1976) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà-Amẹ́ríkà tẹ́lẹ̀rí agbábọ́ọ́lù inú agbọ̀n tí ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ olùkọni fún ẹgbẹ́ bọ́ọ́lù inú agbọ̀n ti àwọn obìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, D'Tigress. Tí a bí ní Portland, Oregon, Udoka parí ilé-ìwé gíga Benson Polytechnic (1994) ní Portland ṣáájú kí ó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga DePaul ní Chicago, Illinois láti ọdún 1994 sí ọdún 1998. Ó jẹ́ ẹ̀gbọ́n sí olùkọni àti òṣèré NBA tẹ́lẹ̀ Ime Udoka. [1]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ime Udoka profile hoopshype.com